Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn

(Àtúnjúwe láti Human Development Index)
World map indicating the Human Development Index (based on 2007 data, published on October 5, 2009)
     0.950 and Over      0.900–0.949      0.850–0.899      0.800–0.849      0.750–0.799      0.700–0.749      0.650–0.699      0.600–0.649      0.550–0.599      0.500–0.549      0.450–0.499      0.400–0.449      0.350–0.399      under 0.350      not available
(Color-blind compliant map) For red-green color vision problems.

Atọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn (AIE tabi HDI; Human Development Index) je statitiki àkópọ̀jáde tounje lilo lati toipo awon orile-ede bii ipele "idagbasoke eniyan" ati lati pinya awon orile-ede adagbasoke (idagbasoke giga), toundagbasoke (idagbasoke arin), ati aitodagbasoke (idagbasoke kekere). Statistiki na je kikopojade lati inu data lori igbe àdúródè, eko ati per-capita GIO tenikookan (gege bi olutoka iru igbesiaye) to je gbigbajo latowo awon orile-ede kookan to si je sise pelu formula yi:

  • atọ́ka- =

nibi ti ati je iye kikerejulo ati gigajulo ti ayipada le ni, ni telentele.ItokasiÀtúnṣe