Human Rights Watch je agbajo aije ti ijoba kariaye kan to un sewadi ati akitiyan fun awon eto omoniyan. Ibujoko re wa ni ilu New York o si ni awon ibi-ise ni Berlin, Brussels, Chicago, Geneva, Johannesburg, London, Los Angeles, Moscow, Paris, San Francisco, Tokyo, Toronto, ati Washington D.C.[2]

Human Rights Watch
IrúNon-profit
NGO
Dídásílẹ̀ ní1978 under the name Helsinki Watch
Adopted current name in 1988.[1]
IbùjókòóNew York City
Òṣìṣẹ́Kenneth Roth, Executive Director
MethodHuman rights, Activism
Ibitàkunhttp://www.hrw.org
 
Oludari alase lowolowo fun Human Right Watch Kenneth Roth hun soro ni 44th Munich Security Conference 2008.

Human Rights Watch je didasile labe oruko Helsinki Watch ni odun 1978 lati mojuto bi orile-ede tele Isokan Sofieti se un tele Awon Ipinnu Helsinki.




  1. "Our History". Human Rights Watch. Retrieved 2009-07-23. 
  2. "Frequently Asked Questions". Human Rights Watch. Retrieved 2009-07-23.