Human trafficking
Àdàkọ:For-multi Àdàkọ:Slavery Àdàkọ:Sex and the law Ìjínigbé káàkiri tí àwọn elédè gẹ̀ẹ́sì ń pè ní Human trafficking jẹ́ Ìfì ènìyàn ṣòwò fún ète iṣẹ́ àfipámúṣe, ìfipápábánilò-ẹ̀ṣẹ̀, tàbí ìṣòwò ìfipábánilòpọ̀.Èyí lè wáyé tàbí ṣẹlẹ láàrín Orílè èdè kàn, ìlú kan tàbí agbègbè kan. Ìfípá jínigbé yatọ pátápátá sí gbígbé èniyàn lọ́nà èèrù kúrò ní ìlú kan lọsí ìlú mìírà á lè pè ní gbígba àṣẹ lọ́wọ ẹnití wọ́n fẹ́ fí ọ̀nà èèrú gbé kúrò ní ìlú kan sí ibòmíràn.[1].
Ní gbogbo àgbayé ni won tí òfin lòdì sí fífipá gbéni lónà àìtọ́, o sí lòdì sí àwọn ẹ̀tọ́ ènìyàn nípasè àwọn àpéjọ àgbáyé, sùgbón ààbò òfin yàtọ̀ ní àwọn ìlú lágbayé. Ìwà náà ní àwon mílíọ̀nù àwọn olùfaragba àti àwọn tí ìrù èyí ti sẹlẹ́ sí káàkiri àgbáyé.
- ↑ "UNODC on human trafficking and migrant smuggling". United Nations Office on Drugs and Crime. 2011. Retrieved 22 March 2011.