Ọ̀jọ̀gbọ́n Humphrey Nwosu (wọ́n bí lọ́jọ́ 2 oṣù October ọdún 1941) jẹ́ alága àjọ ètò ìdìbò, National Electoral Commission (NEC) tí Ààrẹ ìjọba ológun Ibrahim Babangida yàn lọ́dún 1989 sí 1993.[1]

Humphrey Nwosu
Chairman of the National Electoral Commission of Nigeria
In office
1989–1993
AsíwájúEme Awa
Arọ́pòOkon Uya
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹ̀wá 1941 (1941-10-02) (ọmọ ọdún 83)
Anambra State, Nigeria

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Imam Imam (9 June 2010). "Past INEC Chairmen". ThisDay. Retrieved 2010-06-10.