Hussein Shire
Hussein Shire (Lárúbáwá: حسين شاير) jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ ède Somalia nígbà ayé rẹ̀. Òun ni ó ni ilé iṣẹ́ Gateway Bus Company.
Hussein Shire حسين شاير | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1928 or 1929 Galkaio, Somalia |
Aláìsí | 28 June 2014 Johannesburg, South Africa |
Iṣẹ́ | Entrepreneur |
Title | CEO of the Gateway Bus Company |
Olólùfẹ́ | Mariam Hussein |
Àwọn ọmọ | 9 |