Hypertext tàbí Ikokoja jẹ ikọ̀ lórí kọ̀mpútà tàbí ohun ẹ̀rọ afinásisẹ́ míràn, pẹ̀lú àwọn ìtọ́kasí (ijapokoja) sí àwọn ikọ̀ míràn tí olùkàwé lè lò kíákíá, bóyá pẹ̀lú Click èkúté (mouse) tàbí títẹ̀ bọ́tínì lórí pátákó bọ́tínì. Lẹ́yìn pé òun fihàn ikọ̀, hypertext tún lè ní tábìlì, àwòrán àti àwọn ohùn ìfilọ́lẹ̀ míràn. Hypertext ní àjọtúmọ̀ lábẹ́ tó ń ṣe ìtumọ̀ ọ̀pọ̀ World Wide Web, tó mú kó jẹ́ kó rọrùn láti lo àti láti pín ìfitónilétí lórí Internet.[1]

Sistema hipertextual



Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Internet legal definition of Internet". West's Encyclopedia of American Law, edition 2. Free Online Law Dictionary. July 15, 2009. Retrieved November 25, 2008.