INEC card reader
erọ ijẹrisi oludibo eletiriki to ṣee gbe,
(Àtúnjúwe láti INEC CARD READER)
Ẹ̀rọ ìyẹkáàdì-wò ti àjọ INEC náà jẹ́ ẹ̀rọ oníná béléjá fún ìṣàrídájú ìdìbò tí wọ́n ṣe láti máa ṣàyẹ̀wò àwọn Káàdì ìdìbò alálòpẹ́ (PVCs) tí àwọn àjọ tí ó ń bójú tó ètò ìdìbò ní gbogbo orílẹ̀-èdè (INEC) ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe Ẹ̀rọ ìyẹkáàdì-wò náà fún ètò ìdánimọ̀ (ìdá ojúlówó òǹdìbò ṣáájú ìbò dídì mọ̀).[2] Wọ́n ṣe ẹ̀rọ náà láti ṣàyẹ̀wò àwọn káàdì. ìdìbò, PVC ti ibùdó ìdìbò kan ní pàtó àti pé ọjọ́ ìdìbò nìkan ni ó lè ṣiṣẹ́.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Card Reader Controversy, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 2015-03-29. Retrieved 2015-03-28.
- ↑ "INEC Mock poll exposes Card Readers' flaws - Vanguard News". Vanguard News.
- ↑ "Mixed Results Trail INEC's Mock Trial of Card Readers, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 2015-04-02. Retrieved 2015-03-28.