Ibidun Ighodalo
Ibidunni Ighodalo (Oṣù keje ọdún 1980 sí ọjọ́ kẹrìnlá ọdún 2020) jẹ́ yèyé ẹwà kan ti tẹ́lẹ̀, onímọ̀ ìṣàkóso ìṣẹ̀lẹ̀, onínúure, pẹ̀lú olùṣọ àgùntàn ilé ìjọsìn Trinity House ní ìlú Èkó Nàìjíríà. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ Elizabeth R, ilé-iṣé ìbátan gbogbo gbò àti ìṣẹ̀lẹ̀; pẹ̀lú Ibidunni Ighodalo Foundation, agbárí tí kìí ṣe èrè tí ó dojúkọ́ lórí àtìlẹ́yìn àwọn ìdílé pẹ̀lú ìṣòro àìrọ́mọbí.
Ibidunni Ighodalo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ibidunni Ajayi July 1980 Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Aláìsí | 14 June 2020 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Founder and CEO, Elizabeth R, and Ibidunni Ighodalo Foundation |
Ìgbà iṣẹ́ | 1999 |
Gbajúmọ̀ fún | Beauty Pageant (Miss Lux) , Event Management, and Philanthropy |
Notable work | Avant-Garde and Dorchester |
Website | [1] |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀ Àti Ẹbí
àtúnṣeWọ́n bí olóògbé Ibidunni Ighodalo ní Kaduna, ìpínlẹ̀ Kaduna ní ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù keje [1] ọdún 1980.[2] Ò jẹ́ ọmọ karùn-ún ti àwọn ọmọ mẹ́jọ ti olóògbé Olaleye Ajayi.[3]
Ìpìlẹ̀ Ẹ̀kọ́
àtúnṣeIbidunni lọ sí ilé-ìwé K-Kotun fún tó wà ní Surulere ní ìlú Èkó, [3] ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ gírámà ní Federal Government Girls College, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Lẹ́yìn náà, ó gbàwé láti kọ́ Medicine ní Fásìtì ti Èkó èyí tí a mọ̀ sí University of Lagos, Akoka, èyí tí ó jẹ́ àyànfẹ bàbá rẹ̀. Bíbẹ́ẹ̀kọ́, ìwé gbígbà rẹ̀ dàpọ̀ mọ́ ẹlòmìíràn, ó sì pinnú láti ka Microbiology. Nígbà tí o pari òye òye rẹ̀, ó gba ìkẹ́kọ̀ọ́ síwájú síi ní Ìṣàkóso Ìṣòwò láti Ilé-ìwé Ìṣòwò tí ìpínlẹ̀ Èkó. Ó tún jẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ ti National Institute Marketing.
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ "Ibidun Ighodalo: Former beauty queen and wife of popular Lagos pastor dies of suspected heart attack". Pulse Nigeria (Pulse). 14 June 2020. https://www.pulse.ng/news/local/ibidun-ighodalo-former-beauty-queen-and-wife-of-popular-lagos-pastor-dies-of/nm43c7v. Retrieved 26 June 2020.
- ↑ "Ibidunni Ituah-Ighodalo: Bittersweet Memories of a Beloved Enchantress". ThisDayLive (This Day). 21 June 2020. https://www.thisdaylive.com/index.php/2020/06/21/ibidunni-ituah-ighodalo-bittersweet-memories-of-a-beloved-enchantress/. Retrieved 26 June 2020.
- ↑ 3.0 3.1 Maria, Diamond (20 June 2020). "Tears, tributes as Ibidun Ighodalo goes home today". guardian.ng. Guardian Newspaper (Guardian Newspaper). Archived from the original on 22 June 2020. https://web.archive.org/web/20200622172206/https://guardian.ng/guardian-woman/tears-tributes-as-ibidun-ighodalo-goes-home-today/. Retrieved 26 June 2020.