Ibrahim Hamza je oloselu ọmọ Naijiria . Wọ́n yàn án láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò ìjọba àpapọ̀ Soba ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti ọdún 2019 titi di ọdún 2023. [1]

Ibrahim Hamza
Member of the House of Representatives of Nigeria from Kaduna State
In office
2019–2023
ConstituencySoba
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1974
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
OccupationPolitician

Awọn itọkasi

àtúnṣe