Ibubeleye Whyte
Ibubeleye Whyte agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 9, óṣu january ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi goalkeeper fun Rivers Angels ti o si kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ naigiria[1][2][3][4].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ibubeleye Whyte | ||
Ibi ọjọ́ibí | Enugu, Enugu State, Nigeria | ||
Ìga | 1.71m | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Club information | |||
Current club | Rivers Angels | ||
Number | 1 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Rivers Angels | |||
National team‡ | |||
2013– | Nigeria women's national football team | 6 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Whyte kopa ninu Cup FIFA U-20 awọn obinrin agbaye ati ere idije awọn obinrin ilẹ afirica[5].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://globalsportsarchive.com/people/soccer/ibubeleye-whyte/157040/
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/ibubeleye-whyte/260393/
- ↑ https://www.eurosport.com/football/ibubeleye-whyte_prs326799/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/7e3cc31a/Ibubeleye-Whyte
- ↑ https://www.playmakerstats.com/player.php?id=287668