Ichan Kala
Àdàkọ:Infobox UNESCO World Heritage Site Ichan Kala (Àdàkọ:Lang-uz) ìlú tí wọ́n mọdi yíká tí ó wà ní Khival ní Ùsbẹ̀kìstán Ìlú yí ti wà lábẹ́ ìnojúwò ati ìdáàbòbò àjọ World Heritage Site láti ọdún 1990. Ìlú àtijọ́ yí ní àwọn ibi ìtàn ní agbáyé tí ó tó àádọ́ta tí wọ́n sì ti wà láti ọ̀rùndún kejìdínlógún tabí kọkàndínlógún sẹ́yìn. Fún àpẹẹrẹ, Mọ́sálásí Djuma ni wọ́n kọ́ ní àárín ọ̀rùndún Kẹwàá tí wọ́n sì tún Mọ́sálásí náà kí ní ọdún 1788 sí 1789.
Ohun tí ó ṣe pàtàkì jùlọ tí ó fijú hàn ní Ichan Kala ni àwọn bíríkì alámọ̀ tí wọ́n fi mọ géètì yíká ìlú náà. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ti fi ìpìlẹ̀ ìlú náà lélẹ̀ ní nkan bí ọ̀rùndún kẹwàá tí ó jẹ́ 10-metre-high (33 ft) tí wọ́n sì fi ìpìlẹ̀ àwọn odi náà lélẹ̀ ní àárín ọ̀rùndún kẹtalélógún tí wọ́n sì tun ṣe láìpẹ́
Gallery
àtúnṣe-
West gate
-
A street in the Old City
-
Inside the Mausoleum of Pahlavān Mahmoud
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣeÀwọn ìjásóde
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Ichan Kala |
Àdàkọ:Fortresses of Chorasmia Àdàkọ:Tourist attractions in Uzbekistan