Ida B. Wells

(Àtúnjúwe láti Ida Wells)

Ida Bell Wells-Barnett (July 16, 1862 – March 25, 1931) je omo Afrika Amerika oniroyin, olootu iwe-iroyin ati, pelu oko re Ferdinand L. Barnett,[1] ikan ninu asiwaju akoko fun Egbe irinkankan eto omoolu. O se akosile bi Idajopaniyan ni orile-ede Amerika se sele, be sini o kopa ninu egbe irinkankan fun awon eto obinrin ati egbe irinkankan fun eto didibo fun awon obinrin.

Ida B. Wells
Ọjọ́ìbí(1862-07-16)Oṣù Keje 16, 1862
Holly Springs, Mississippi
AláìsíMarch 25, 1931(1931-03-25) (ọmọ ọdún 68)
Chicago, Illinois
Ẹ̀kọ́Freedman's School, Rust College, Fisk University
Iṣẹ́Civil rights & Women's rights activist
Olólùfẹ́Ferdinand L. Barnett
Parent(s)James Wells
Elizabeth "Izzy Bell" Warrenton