Idiat Aderemi Amusu ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má jẹ́ enginia fún ohun ọ̀gbìn ni Nàìjíríà, òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ ni ẹgbẹ́ Council for the Regulation of Engineering in Nigeria. Wọn bíi Idiat ni ìpínlè Kano ni ọjọ́ kẹtàdínlógbon oṣù kọkànlá ọdún 1952.[1] Ó wá láàrin àwọn tí ó kọ́kọ́ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Association of Professional Women Engineers of Nigeria (APWEN) ni ọdún 1983.[2][3][4]

Idiat Amusu
Ọjọ́ìbí1952
Iṣẹ́Engineer

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ St Theresa College ni Ìbàdàn àti Baptist High school ni Ìwọ. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Nigeria, Nsukka níbi tí ó tí gboyè B. Sc nínú agricultural engineering ni ọdún 1978. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má di enginia fun ohun ọ̀gbìn ni Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún Nigerian Society of Engineers, Nigeria Institution of Agriculture Engineers àti Nigeria Institute of Food Science and Technology.[3]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ó darapọ̀ mọ́ Ilé iṣẹ́ ADFARM Ltd gẹ́gẹ́ bí olùdarí. Ó di olùkọ́ fún ìṣirò ni ilé ẹ̀kọ́ Epe Grammar School àti Our Lady of Apostles Secondary school ni ìlú Èkó. Ní ọdún 1982, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Yaba College of Technology níbi tí ó tí ń kọ ìṣirò fun àwọn akẹ́kọ̀ọ́ enginia. Ó di olórí fún ẹkà tekinology fún oúnjẹ ní ọdún 1996 di 1998 ni ilé ẹ̀kọ́ gíga náà.[5][6][7] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún Council for the Regulation of Engineering in Nigeria, Nigerian Society of Engineers, Association of Professional Women Engineers in Nigeria (APWEN)[8], Nigerian Society of Engineers, Nigerian Institution of Agricultural Engineers ati Nigerian Institute of Food Science and Technology.[9][10][11] Ní ìrántí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí ó ti ṣe, NSE wá ṣe eto ìdíje tí wọn pè ní Project Skill Competition tí wọn sì má ń ṣe ní ekan lọ́dún láti lè yẹ síi. Ètò nan má wáyé ní ìpínlè Èkó, ó sì wá fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ni Secondary school.[12][13][14][15]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Celebrating Engr (Mrs) Idiat Amusu, an Ex-Student of St. Teresa's College and Past Coordinator of STCOGA Lagos Chapter". [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "‘We will improve prospects of potential engineers’". 11 June 2018. Archived from the original on 18 April 2021. Retrieved 19 May 2020. 
  3. 3.0 3.1 "Idiat Amusu, First Female Graduate of Agricultural Engineering in Nigeria: Celebrating an engineer per excellence". My Engineers. 27 November 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Joanna Maduka lecture holds today". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-08. Archived from the original on 18 September 2020. Retrieved 19 May 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Gbonegun, Victor (20 May 2019). "Engineers groom students in project, technology designs". The Guardian. Archived from the original on 1 December 2020. Retrieved 19 May 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "YABATECH "Reverse Engineering: Panacea To Waste, Not Want Not"- Idiat Amusu". My Engineers. 5 June 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Pawsey, Rosa K. (9 May 2002). "Case Studies in Food Microbiology for Food Safety and Quality". Royal Society of Chemistry – via Google Books. 
  8. "4th Apwen President". APWEN. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "Limbs For Life Nigeria". limbsforlifenigeria.org. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  10. "Women Engineers, NNPC give 9 year-old, 9 other girls scholarships to university level". Global Patriot News.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. "Google Scholar". scholar.google.com. 
  12. "Ikeja Engineers to Honour Idiat Amusu as Branch organizes Project Skill Competition for Schools". My Engineers. 13 May 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. "Keke High School Emerges Winner Of The Idiat Amusu Project Skill Competition 2019 -". 16 May 2019. 
  14. "Amusu: The Society Was Not Prepared To Employ Female Engineers -". 18 May 2019. 
  15. Alegba, Grace (16 May 2019). "NSE begins grooming next generation young engineers to lead Nigeria’s technology revolution".  Unknown parameter |url-status= ignored (help)