Idibo gomina ipinle Eko lodun 2011

Idibo gomina ipinle Eko lodun 2011 je eto idibo dun ipo gomina keje ni ipinle Eko . To waye ni ojo kerindinlogbon osu kerin odun 2011, omo egbe Action Congress of Nigeria Babatunde Fashola jawe olubori ninu ibo naa, ti o bori Shamsideen Adegboye ti People's Democratic Party .[citation needed][1]

Apapọ awọn oludije marun din logun ni wọn dije ninu idibo naa. Babatunde Fashola lati egbe Action Congress of Nigeria lo jawe olubori ninu ibo naa, o bori Shamsideen Adegboye lati egbe People’s Democratic Party . Awọn ibo to wulo jẹ 1,862,513.[citation needed]

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. https://africanelections.tripod.com/ng_2011governor.html