Idris Akọkọ ti Morocco
Idris (akọkọ) ibn Abd Allah (Èdè larubawa: إدريس بن عبد الله, Èdè Roman: Idrīs ibn ʿAbd Allāh) ni a tumọ si Idris Agba (Èdè Larubawa: إدريس الأكبر, Èdè Roman: Idrīs al-Akbar), (d. 791) jẹ ara larubawa Hasanid Sharif ati oludari Idrisid dynasty ti northern Morocco pẹlu ajọṣèpọ ẹya Berba ti Awraba, lẹyin ti wọn sa ni Hejaz latari ogun ti Fakhkh.
Idris I ibn Abd Allah إدريس بن عبد الله | |
---|---|
Emir of Morocco
| |
Reign | 788–791 |
Predecessor | None |
Successor | Idris II of Morocco |
Spouse | Kenza al-Awrabiya |
Issue | |
Idris II of Morocco | |
Full name | |
Idris ibn Abd Allah ibn al-Hasan ibn al-Hasan ibn Ali | |
Father | Abd Allah al-Mahd |
Mother | Atika bint Abd al-Malik |
Born | Unknown Arabian Peninsula |
Died | 791 Volubilis |
Burial | Moulay Idriss Zerhoun |
Igbesi Àye Idris Akọkọ
àtúnṣeIdris akọkọ jẹ ọmọ ọmọ Hasan, ọmọ Fatima ati Ali, ọmọ ọmọ anọbi Muhammad. A bisi ilẹ Arabia. Idris fẹ Kenza ti Awraba tosibi ọmọ kan, Idris keji ti Morocco. Eyi lo mu idasilẹ Idrisid dynasty, ipinlẹ musulumi kẹrim ni Morocco lẹyin Nekor (710–1019), Barghawata (744–1058), ati Midrar (757–976).
Idris I jagun ba awọn apa ibi to tobi ni ariwa ilẹ Morocco to si da agbegbe ti Fez silẹ. Ni ọdun 1789 AD, Idris jagun ba Tlemcen lati Sufrite Ifranid Abu Qurra eyi lo mu ki Abbasid caliph Harun al-Rashid gbẹsan to si awọn agbenipa si. Idris akọkọ ku ni ọdun 1791 ni Walīlī. Idris keji, ọmọ rẹ ni a bini óṣu melo kan sẹyin ti Awraba si re dagba ni abẹ̀ adele baba rẹ Rashid. Ni ọdun 1808, o kuro ni Walīlī lọ si Fes, nigba idari rẹ̀ (791–828), o sọ Fez di ilu nla
Wọn si Idris akọkọ si oke kan ti ko jina si Walīlī. Tubu rẹ gun lọsi Abulè kan ti a n pè ni Moulay Idriss Zerhoun. Ilè ẹsin Zawiya ni agbegbe mausoleum gboro ni bẹ fun aimoye ọdun to si pada di ilè ẹsin pataki ni ilẹ Morocco.