Ifako International School
A ṣe ìdásílẹ̀ Ifakọ International Schools ní ọdún 1974 ní Ifako-Ijaiye, Ifakọ, ní ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà. Ilé ẹ̀kọ́ náà ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti gírámà.
Ìtàn
àtúnṣeNí ọdún 1975, ilé-ẹ̀kọ́ náà parí kíláàsì rẹ̀ àkọ́kọ́. Nígbàtí ó sì dì ọdún 1978, ìjọba ìpínlè Èkó fọwọ́sí ilé-ẹ̀kọ́ Ifakọ International School gẹ́gẹ́bí eto ilé-ẹ̀kọ́ giga. .Lati ọdún 1982 títí di ọdún 1983, òfin ìjọba ìpínlè Èkó kò jẹ́ kí ilé-ẹ̀kọ́ náà kópa nínú ìdánwò àwọn ilé-ẹ̀kọ́. Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìkópa nínú ìdánwò padà ní ọdún 1984.