Ifeoma Onyefulu

Onkọ̀wé

Ifeoma Onyefulu tí wọ́n bí lọ́dún 1959 oǹkọ̀wé ọmọdé, oǹkọ̀wé ìtàn-àròsọ àti afẹ̀rọyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká nípa ìwé àwòrán rẹ̀ tí ó ṣe fi ṣe àfihàn ìgbésí ayé rẹ̀ abúlé rẹ̀ nílẹ̀ adúláwò Afíríkà.[1][2]

Wọ́n bí Ifeoma ní ìlú Onitsha, ní Ìpínlẹ̀ AnambraNigeria.[1]Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìran Ìgbò ni Nigeria, ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní United Kingdom. Ó jẹ́ oṣìṣẹ́ ayàwòrán fún ìwé ìròyìn, Caribbean Times from 1986-87.[2]

Àwọn ìwé rẹ̀

àtúnṣe
  • A Is for Africa: An Alphabet in Words and Pictures, Cobblehill Books (New York, NY), 1993.[3]
  • Emeka's Gift: An African Counting Story, Cobblehill Books (New York, NY), 1995.[4]
  • Ogbo: Sharing Life in an African Village, Cobblehill Books (New York, NY), 1996, published as One Big Family: Sharing Life in an African Village, Frances Lincoln (London, England), 1996.[5]
  • Chidi Only likes Blue: An African Book of Colors, Cobblehill Books (New York, NY), 1997.[6]
  • Grandfather's Work: A Traditional Healer in Nigeria, Millbrook (Brookfield, CT), 1998, published as My Grandfather Is a Magician: Work and Wisdom in an African Village, Frances Lincoln (London, England), 1998.[7]
  • Ebele's Favourite: A Book of African Games, Frances Lincoln (London, England), 1999.[8]
  • A Triangle for Adaora: An African Book of Shapes, Dutton Children's Books (New York, NY), 2000.[9]
  • Saying Goodbye: A Special Farewell to Mama, Millbrook (Brookfield, CT), 2001.
  • Welcome Dede!: An African Naming Ceremony, Frances Lincoln (London, England), 2003.
  • Here Comes Our Bride!: An African Wedding Story, Frances Lincoln (London, England), 2004.
  • African Christmas, Frances Lincoln (London, England), 2005.[2]

Àwọn àmìn-ẹ̀yẹ tí ó ti gbà

àtúnṣe

Ìwé àwọn ọmọdé rẹ̀ kan tí ó kọ́ pẹ̀lú àkọ́lé, A is for Africa,ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ àwọn ọmọdé tó dára jù lọ.[10] Bẹ́ẹ̀ náà ló gbàmìn-ẹ̀yẹ ìwé àwọn ọmọdé tí Africana Book Award, fún ìwé rẹ̀, Here Comes the Bride lọ́dún 2004 àti fún ìwé rẹ̀, Ikenna Goes to Nigeria lọ́dún 2007.[11] Bákan náà, ó gbàmìn-ẹ̀yẹ fún ìwé ọmọdé ni orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà fún ìwé rẹ̀, Here Comes the Bride lọ́dún 2005 àti fún Ikenna Goes to Nigeria lọ́dún 2008.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Biography of Ifeoma Onyefulu". www.ifeomaonyefulu.co.uk. Archived from the original on 2018-09-03. Retrieved 2018-05-24. 
  2. 2.0 2.1 2.2 "Ifeoma Onyefulu." Gale Literature: Contemporary Authors, Gale, 2007. Gale Literature Resource Center
  3. "Ifeoma Onyefulu (1959-) Biography - Personal, Addresses, Career, Writings, Sidelights". biography.jrank.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-27. 
  4. "Children's Book Review: Emeka's Gift: An African Counting Book by Ifeoma Omyefulu, Author, Ifeoma Onyefulu, Author, Alex Ayliffe, Illustrator Dutton Books $14.99 (32p) ISBN 978-0-525-65205-2". PublishersWeekly.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-27. 
  5. "Ogbo - Ifeoma Onyefulu". buchindan13.gotdns.ch. Retrieved 2020-05-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. Onyefulu, Ifeoma (1997). Chidi only likes blue an African book of colors (1st American ed.). New York Cobblehill Books. ISBN 978-0-525-65243-4. https://trove.nla.gov.au/work/8568568. 
  7. "Ifeoma Onyefulu (1959-) Biography - Personal, Addresses, Career, Writings, Sidelights". biography.jrank.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-27. 
  8. "Ebele's Favourite: A Book of African Games by Onyefulu, Ifeoma Paperback Book 9781845071868". eBay (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-27. 
  9. Johnson, Nancy J.; Giorgis, Cyndi (2001). "Children's Books: Interacting with the Curriculum". The Reading Teacher 55 (2): 204–213. ISSN 0034-0561. JSTOR 20205032. 
  10. "Ifeoma Onyefulu | Penguin Random House". PenguinRandomhouse.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-02. 
  11. "CABA Winners". Africa Access (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-22. Retrieved 2020-04-02.