Ify Ibekwe

Agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Ifunanya Debbie ti ọpọlọpọ eniyan mọ si ''Ify Ibekwe'' ti wọn bi ni ọjọ karun un oṣu kẹwa ọdun 1989 je ọmọ orile-ede Naijiria ati Amerika ti o agbabọlu alapẹrẹ fun ikọ Virtus Eirene Ragusa ati iko agbaboolu alapere orile-ede Naijiria (Nigeria women's national team)

Arizona statistics

àtúnṣe
Legend
  GP Games played   GS  Games started  MPG  Minutes per game
 FG%  Field goal percentage  3P%  3-point field goal percentage  FT%  Free throw percentage
 RPG  Rebounds per game  APG  Assists per game  SPG  Steals per game
 BPG  Blocks per game  PPG  Points per game  Bold  Career high
Year Team GP Points FG% 3P% FT% RPG APG SPG BPG PPG
2007–08 Arizona 24 249 47.3 53.2 8.0 0.6 1.1 1.3 10.4
2008–09 Arizona 29 456 45.9 25.0 66.1 11.6 1.1 2.1 1.8 15.7
2009–10 Arizona 31 434 47.2 35.3 61.8 11.4 2.2 2.2 1.2 14.0
2010–11 Arizona 32 514 47.8 42.4 70.2 9.8 1.9 2.3 1.5 16.1
Career Arizona 116 1653 47.0 38.9 64.4 10.3 1.5 2.0 1.4 14.3

Seattle Storm yan Ibekwe sinu ipele idije elekeji 2011 WNBA draft (24th overall) elekeji .

National Team Career

àtúnṣe

Ify ṣoju iko awon obinrin agbaboolu alapere orile-ede Naijiria (Nigerian Womens National Team).[1]

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Agatha ati Augustine Ibekwe ti won obi ify je omo orile-ede Naijiria . Bee naa ni o ni awon aburo okurin ti awon naa je agbaboolu alapere. Okan lara awon aburo re ti oruko re n je Onye Ibekwe ni o n gba boolu alapere jeun fun Long Beach State, nigba ti Ekene Ibekwe n gba boolu alapere jeun funp iko University of Maryland. Bakan naa ni o tun ni omo iya obinrin ti oruko re n je Chinyere.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àwọn ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:2011 WNBA Draft