Igbó àárín Cross River àti odò Niger
Igbó àárín Cross River àti Niger jẹ́ tí ó wà ní àárín Ìpínlẹ̀ Cross River àti odò Niger ní apá gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà.[1]
Bí igbó náà ṣe rí
àtúnṣeIgbó náà tàn dé àwọn Ìpínlẹ̀ bi Abia, Akwa Ibom, Anambra, Ebonyi, àti Imo, ilẹ̀ tí ó gbà sì tó 20,700 square kilometers (8,000 sq mi).
Àdúgbò ibè ní omi, ìgbà ẹrùn ibẹ̀ sì jẹ́ láàrin oṣù Kejìlá sí oṣù kejì.
Wàhálà tí ó búyọ ní àdúgbò igbó náà
àtúnṣeÀdúgbo tí igbó náà wà jẹ́ àdúgbò tí ó ti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùgbé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, èyí mú kí wón ma gé àwọn igi inú igbó yìí lulẹ̀ fún iṣẹ́ àgbẹ̀, láti kólé síbẹ̀ àti fún àwọn ǹkan míràn bi kí kó ilé ìṣẹ́ fún ṣíṣe epo rọ̀bì ní Port Harcourt. Àwọn igbó sì wà ní Ìpínlẹ̀ Anambra àti àwọn ibọ̀ míràn ṣùgbọ́n àwọn wọ́n gbin àwọn igi sínú igbó nítorí kí wọ́n le gé wọn láti ṣe pákó.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Map of Ecoregions 2017" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Resolve. Retrieved August 20, 2021.