Igbó òkè Cameroon
Igbó òkè Cameroon jẹ́ àwọn igbó tí ó wà ní àwọn òkè Gulf of Guinea tí ó sì pàlà láàrin orílẹ̀-èdè Cameroon àti Nàìjíríà. Agbègbè ibè kún fún àwọn igi àti koríko, àwọn igi ibè ń díkù si, àwọn koríko rẹ̀ ń sì pò si nítorí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n ń ṣe níbẹ̀.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Map of Ecoregions 2017" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Resolve. Retrieved August 20, 2021.
- ↑ "Cameroonian Highlands forests" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). The Encyclopedia of Earth. Retrieved August 20, 2021.