Igbó Olodùmarè

Igbó Olódùmarè jẹ́ ìwé-ìtàn àròsọ méèrírí tí Ọgb́eni Daniel O. Fágúnwà. Ó jẹ́ ìwé-ìtà àròsọ àkọ́kọ́ tí a kọ lédè Yorùbá àti ní ilẹ̀ adúláwò ̣Áfíríkà. A kọ ó ní ọdún 1949, Òun sì ni ìwé-ìtàn àròsọ kejì òǹkọ̀wé náà, Daniel O. Fágúnwà.[1]

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "D.O. Fagunwa". Brittanica. Retrieved 28 September 2011.