Igbeyawo ipa je ohun kan ti owopo ni ilu naijiria ni to ri wipe ijoba apapo ati ijoba ipinle o tii fi awon ofin lele lati daa duro, ni eto omode wi.

Àpẹẹrẹ ìgbéyàwó ipá

Ilu naijiria je ilu ti igbeyawo ipa wopo ju ni ile alawo dudu, eto omo eniyan. ofin eto awon omode lodi si igbeyawo omo ti ko to omo odun mejidini ogun. olodi si ofin ilu nigeria. awon ipinle ti ofin ati ilana musulumi ti gbile kuna lati ti gba pe ofin ijoba apapo to wipe omo gbodo pe omo odun mejidi ni ogun ki o gbeyawo tabi ki o to lo si ile oko.

oje ohun ti o bani ninuje lati gbo pe ni nkan bi ogun odun lehin ti ijoba ti fi ofin lele nipa eto omode, sibe-sibe, won si n fi awon omodebinrin fun oko tipatipa ni ilu nigeria . Awon ijoba ipinle ni ilu naijiria gbodo bere ni pajawiri lati gba awon ofin ati ilana igbewayo wole pelu ilana ati eto awon omode.

Ni osu kejo ati Osu kewa ni odun 2021, awon osise eto omoniyan se iforowani lenu wo lati odo awon omobirin ti odun won bere lati odun merinla de mokandinlogun, apapo awon ajo ti kiise ti ijoba nsise takuntakun lati ri ni aridaju wipe won fi opin si igbeyawo awon omode ati ifiyajeni ninu igbeyawo ni ipinle imo ati kano.

Ipa awon egbe ajafeto omoniyan

àtúnṣe

Egbe apapo awon ti o mmoju to eto omo eniyan se asayan ipinle Imo ati kano ni to ri orisihrishi asa, ofin ati ilana, won kowe ranshe si eka ijoba ti won mojuto awon obinrin lati le se iforo wa ni lenuwo sugbon ko si ifesipada.

Olodi si ofin ni ilu naijiria ati ni ile alawodudu lati fi omobirin ti ko ti to omo odun mejidi ni ogun fun iyawo.

Eri fi han wipe ni ilu Imo and Kano, awon odomobirin oki fibe ni ominira lati ka iwe, lati mojuto ilera arawon atiwipe ko fibee si abo ti onipon fun awon obinrin, ninu awon odomobirin ti won fe fifun oko fi ogbon yera.

Ni ipinle Imo ti pupo ninu won nse esin christiani to je ede igbo ni won ma nso gba ofin eto awon omode wole ni odun 2004, awon odomobinrin won ni awon ebi won lo sabi ma nti won si igbeyawo ipa.

Ninu ofin sharia ni ipinle kano, eri fi han wipe ibe ni igbeyawo ipa posi ju ni orile ede Nigeria, ile igbimo agba Ipinle Kano buwo lu abadofin aabo lori awon omode ni inu osu keji odun 2021, gegebi o ti wa ni ibamu pelu ofin ati ilana awon orile-ede agbaye.

Ni ipinle Kano, awon ajo ati won moju to eto omo eniyan wipe awon ebi ma nfi awon obinrin fun oko lai jeki won mo nka ti o ye ki won mo ni pa eni ti won fefe, ilana ati asa igbeyawo won je nka ti oni se pelu ofin sharia, ofin esin, ati ofin ibile ni tori wipe awon obinrin ko ni anfani lati se ipinnu ara eni.

Awon obi mi so wipe, awon inowo ma ndiku ti won ba tete fi awon omobinrin won fun oko, awon omobinrin imi ni wipe ipo nkan ma nnira fun awon lehin igbeyawo, awon imi oki kawe nitori wipe kosi owo, awon oko imi o kii fe ki iyawo won ma se ise osu.

Oje ohun pajawiri fun orile ede Nigeria lati se ofin lati file ma daabobo awon omobirin kuro lowo awon afipa fun ni loko ni eto omo eniyan wi.

Ofin eto omode gbodo je ohun ti gbogbo ipinle ati eka gbodo gba towo tese, won gbodo ri ni aridaju wipe gbo eyan mo nipa ohun ti ofin na wi ati iya ti won yo fi je enikeni ti oba tapa si ofin naa.

Nitori igbeyawo ipa ti owopo ni ipinle imo ati kano, ose pataki lati jeki gbogbo eniyan ni orile ede nigeria mo ni pa awon ofin ati ilana igbeyawo tobojumu ati abo to peye fun awon odomobinrin ni orile ede nigeria.

Fun awon eri aridaju ati ayewo to peye, ale kansi ifipa fo mobinrin foko ni orile ede nigeria asa ni ilana esin, ati asa,

Ifipa fo mo fun igbeyawo je ohun ti owo po ni orile nigeria ju ilu kilu lo ni ile alawodudu.

Agbajopo Ijoba agbaye ni ipade won ni odun 2020 wipe ida metalelogoji awon odomobinrin ti won je omo odun ogun ati merinlelogun ni won ti fifun igbeyawo ni orile ede nigeria.

ifipa fi obinrin fun oko je ohun ti ma ni damu won ni gbogbo ona ni igbesi aye won.

Ijoba orile ede nigeria ati ijoba ipinle ni ipa ti won gbodo ko pelu agbajopo ijoba ile alawodudu and agbajopo ijoba kari agbaye gege bi ofin ti wi.

ipinle mokanla ninu ipinle mefalelogbon ni orile ede nigeria ni won ko ti gba ofin eto omode wole si ipinle won.

Ilana ati ofin isin musulumi ni awo ariwa na tun dakun popo ninu isoro fifi awon odomobirin kekee fun oko ati asa idabe pelu gbogbo isapa orile ede nigeria lari ri pe won se ohun gbogbo ni ilana ati ofin agbaye.

eri fi han wipe ni ilu ariwa ni orile ede nigeria, ida mejidi ni ogorin awon obinrin ti ma si ile oko ki won to di omodun mejidiniogun.

Awon egbe to mo ju to eto omo eniyan se awaridaju lodo awon elesin musulumi eka ariwa ati elesin christiani ni eka gusu orile ede nigeria wipe.

Eto nlo ni ilu kano lati ri ni aridaju wipe abo to peye wa fun awon odomobirin atipe wipe won gbodo da asha fifi awon odomobinrin to won ti pe odun mejidilogun foko ni idaduro.

Awon asofin gbodo sapa lati ri wipe awon ofin won fi aye fun idaabobo awon ti won je omodun mejidiniogun https://www.vanguardngr.com/2021/02/kano-approves-child-rights-act-awaits-passage-of-bill-from-assembly/

Ipinle imo je okan lara ipinle ti won koko gba asa eto awon omode wole, ni ojo kerin, osu kejo odun 2014, ede igbo ni won ma nso ni ilu imo, pupo niniu won ni won ma nse esin christiani. eri fi han wipe won ti pari ise won nipa didabobo won odomobirin kuro lowo awon afipa foko fun ni.

Ni ilu Imo, oje ohun ti olodi si ofin ibile fun obinrin lati loyun lai loko to ba si ti ri be, won ni lati wa okunrin agbalagba fun to onfe lati fe iyawo ki omo won le ni baba.

Opolopo awon odomobinrin ti won fi fun oko lehin igba ti won ti loyun ni awon obi won ni wipe won ti ba asa ati ise ibile je, won ko si ni fi aye sile fun awon ebi won lati gba owo ori won.

Racheal je odomobinrin omo marundinlogun lati ilu Imo, ore kun re fun ni oyun nigba ti osi nlo si ile iwe grammar lowo, osa jade lati ma lo gbe ninu ile alakoku fun ose meji lai le pada si ilewe mo.

mosa jade nitori iberu pe mo loyun nitori wipe isoro yen yo ti poju ti mo ba ngbe pelu awon molebi mi, asemi ni anfani tim nmba fe oko.

pelu iranlowo awon egbon ati aburo re, o ma npa da sile ni nkan bi agogo meji oru lati wa je onje ale nigba ti ibinu awon obi re bati lole die.

Lehin igba ti orekunrin ti o fun loyun jaakule, awon obire wa oko miran fun latin pa oruko idile won mo, lai pe osu kan, ofe okunrin kan to o je omo ogbon odun to san naira marundin ni ogun fun awon obi re gege bi owo ori, owun ati odomokunrin naa ko ri ra won ri titi nkan be ose meji si ojo igbeyawo won.

Odomokunrin na ni mo fi oju kan ni igba akoko ni ile baba, mo si bere lowo iya mi pe tani eniyen, iya mi wipe oko mi niyen, omo ogbon odun ni, mi o ni ni anfani lati maa gbe ile awon obi mi mo pelu awon omo mi, odidandan fun mi lati lo maa gbe pelu oko mi, mi o si fe si.

Odomobinrin Obinna je omo odun marundinlogun, eni to funloyun je oluko ni ileiwe re, omodun ogota ni igba ti o nlo si ile iwe grammar, awon obi re dawo riran lo si ile iwe duro, won si le si ita.


Awon itokasi

àtúnṣe