Igbó Olódùmarè

(Àtúnjúwe láti Igbo Olodumare)

Igbo Olodumare ni oruko iwe ti D.O. Fagunwa ko.

Eléyìí jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìtàn àròsọ tí D.O. Fagunwa kọ. Ó sọ nípa ìtàn Olówó-ayé àti ìrìnàjò rẹ̀ lọ sí Igbó olódùmarè. Ó sọ bí ó ṣe dé ọ̀dọ̀ bàbá-onírùngbọ̀n yẹ́úkẹ́ àti bí ó ṣe rí òpin Òjòlá-ìbínú

  • D.O. Fagunwa (1950), Igbó Olódùmarè. Nelson Publisher Ltd in association with Evans Brothers (Nigeria) Publishers Ltd; Ìbàdàn, Nigeria. ISBN 978-126-241-9. Ojú-ìwé 165.



Àwọn Itọ́ka sí

àtúnṣe