Igho Charles Sanomi ( wọ́n bí i ní 17 May 1975) ó jẹ oníṣòwò, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, onímọ̀ - ìjìnlẹ̀, sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ àti onínúure tí ó ní ìfẹ́ nínú okoòwò epo, ẹ̀ka iṣẹ́ agbára, ẹ̀ka ìgbòkègbodò, ẹ̀ka ìbáraẹnisọ̀rọ̀, ilé-iṣẹ́ orí omi òkun, ilé iṣẹ́ ọkọ̀ òfurufú àti ilé iṣẹ́ tó ń rí sí àwọn ohun ìní.

Igho Charles Sanomi
Sanomi in 2013
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kàrún 1975 (1975-05-17) (ọmọ ọdún 49)
Agbor, Delta State, Nigeria
Iṣẹ́Businessman and geologist
Gbajúmọ̀ fúnfounding Taleveras
Websiteighosanomi.com

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Igho Charles Sanomi II ni wọ́n bí ní 17 May 1975, [1][2] ní ìlú Agbor, ní Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà. Òun ni ọmọ karùn-ún àti ọkùnrin àkọ́kọ́ tí àwọn òbí rẹ̀ bí.[3] Bàbá rẹ̀, Dickens Ogheneruemu Patrick Sanomi, ni igbá-kejì (ẹlẹ́ẹ̀kejì) Ààrẹ̀ Urhobo Progress Union (UPU) àti ọ̀gá ọlọ́pàá tó ti fẹ̀yìntì, ní Nigeria Police Force.[4][5][6] Ìyá rẹ̀ ni Mabel Iyabo Sanomi, tí ó jẹ́ yeye jemo (olóyè ìbílẹ̀) ti ìlú Isotun Ijesha, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, tí ó wà ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ sì ni ìyá rẹ̀ jẹ́ nọ́ọ̀sì nígbà kan rí. Sanomi gba oyè bachelor's degree nínú ẹ̀kọ́ geology and mining ní University of Jos, Plateau State, ní Ààrin-Gbùngùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[7]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "New owners emerge for Afam Power Plc, Kaduna Distribution Company". Vanguard. 1 August 2013. http://www.vanguardngr.com/2013/08/new-owners-emerge-for-afam-power-plc-kaduna-distribution-company/. 
  2. "Nigerians Win Big in Crude Oil Lifting Contracts". ThisDay. 3 July 2012. Archived from the original on 18 May 2013. https://web.archive.org/web/20130518035159/http://www.thisdaylive.com/articles/nigerians-win-big-in-crude-oil-lifting-contracts/119226. 
  3. "Project 'Touch a life today' launched". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 May 2017. Retrieved 30 May 2020. 
  4. "Police Games: Golfers set for Sanomi tourney". The Punch. 3 March 2013. Archived from the original on 5 March 2013. https://web.archive.org/web/20130305032343/http://www.punchng.com/sports/police-games-golfers-set-for-sanomi-tourney/. 
  5. "Police Games 2013: Dickens Sanomi Championship Kicks Off". ThisDay. 17 February 2013. Archived from the original on 8 May 2014. https://web.archive.org/web/20140508133112/http://www.thisdaylive.com/articles/police-games-2013-dickens-sanomi-championship-kicks-off/139707/. 
  6. Olawale Ajimotokan (4 March 2014). "Bada, Sanomi Bag Police Posthumous Sports Award". ThisDay. Archived from the original on 27 May 2014. https://web.archive.org/web/20140527215710/http://www.thisdaylive.com/articles/bada-sanomi-bag-police-posthumous-sports-award/172979/. 
  7. "Igho Sanomi: Bravery Against The Odds". THISDAYLIVE. 14 October 2022. Retrieved 2 June 2023.