Ijeoma Nwaogwugwu
Ijeoma Nwogwugwu jẹ́ òǹkọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ alákòóso ti Arise TV, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ìwé-ìròyìn Thisday. Ó jẹ́ ayẹ̀ròyìn wò bákan náà ní ìwé-ìròyìn THISDAY.[2][3] Ó jẹ́ òǹkọ̀ròyìn-bìnrin kejì nínú ìtàn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bíi ayẹ̀ròyìn wò ní ìwé-ìròyìn national, ènìyàn àkọ́kọ́ Doyin Abiola.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ijeoma Nwogwugwu, Arise TV MD, named most powerful woman journalist in Nigeria". TheCable. May 30, 2020.
- ↑ "In Nigerian Newspapers, Women Are Seen, Not Heard". Nieman Reports.
- ↑ Nwabueze, Chinenye (10 February 2020). "30 Powerful Female Editors in Nigeria's Press History – MassMediaNG". Archived from the original on 25 March 2023. Retrieved 25 March 2023.
- ↑ "Women's Day: Nigerian Women's Trailblazing Heels of Change". March 7, 2021.