Ikechukwu Amaechi (A bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kínnií ọdún 1967) ó jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria, akọ̀wé àti oníṣòwò. Ó jẹ́ olùdásìlẹ̀ ìwé ìròyiǹ TheNiche lórí aýe lujára. Ó wá láti ìjọba ìbílẹ̀ Ahiazu-Mbaise ní ìpínlẹ̀ Imo, Naijiria.[1][2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Ikechukwu Amaechi ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù kínnií ọdún 1967. Ó wá láti ìlú Ekwereazu tí ìjọba ìbílẹ̀ Ahiazu-Mbaise ní ìpínlẹ̀ Imo, Naijiria.[4] Ó jẹ́ àkọ́bí nínú àwọn ọmọ méjọ, okùnrin mẹ́rin àti obìrin mẹ́rin tí àwọn óbì rẹ̀ Nze Alexander, Amadikwa Amaechi bì. Bàba Ikechukwu jẹ́ akọ́sẹ́mọṣẹ́ olùtajà nígbà tí ìyá rẹ̀ Ezinne Appolonia Agbonma Amaechi jẹ́ olùkọ́.[5]

Ikechukwu Amaechi ti se ìgbéyalwó pẹ̀lú Chioma lé ní ogún ọdún, wọ́n sì bí ọmọ mẹ́ta.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Totally Real with Ikechukwu Amaechi Archives". Vanguard News. 2023-03-25. Retrieved 2023-03-25. 
  2. Egbu, Ralph (4 September 2022). "Ikechukwu Amaechi, Niche and annual lecture" (Column). The Sun. Retrieved 20 October 2022. 
  3. Ogbuehi, Emma (10 October 2022). "Ikechukwu Amaechi: The Man Behind TheNiche". Independent Nigeria. Retrieved 10 October 2022. 
  4. "Ikechukwu Amaechi, The Man Behind TheNiche". NewsProbe. Retrieved 2022-10-13. 
  5. "Ikechukwu Amaechi Biograghy, Early life and Journalism Career". QED.NG. Retrieved 2022-10-21.