Ikechukwu Francis Okoronkwo
Ikechukwu Francis Okoronkwo (tí wọ́n bí ní 27 May 1970) jẹ́ ayàwòrán, agbẹ́gilére àti òǹkọ̀wé ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeIkechukwu ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Ẹ̀bìbì, ọdún 1970 sínú ìdílé Francis Okoronkwo ní Oguta, Nàìjíríà. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Ifáfitì ti Port-Harcourt ní ọdún 1995, ní ọdún 2001, ó gboyè M.A. láti Ifáfitì Nsukka ilẹ̀ Nàìjíríà[2][3][4]
Ìṣàfihàn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeIkechukwu Francis Okoronkwo ti ṣe àfihàn isẹ́ rẹ̀ káàkiri bí i; Created For A Purpose (With David Enyi) B.V.L, Port-Harcourt 1997, Terrain Of The Mind Ondo. Ondo State 1996,Views (With Jumah Ibeagbazi) Alliance Francaise, Kaduna State 2004, A Village Square. Omega Gallery, Sheraton Hotels and Towers Abuja 2005, DUTA, Biennale des Arts Visuels, Bonapriso Center For the Arts. Douala, Cameroon 2007, A Glimpse into Nigerian Art. Cheikh Anta DIOP University, Dakar, Senegal 2006.[5][6]
Àwọn àkọ́sílẹ̀ rè
àtúnṣeIkechukwu Francis Okoronkwo kọ́kọ́ ṣe àgbéjáde ìwé tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Petals and Thorns.[7] Ìwé yìí jẹ́ àkójọpọ̀ ewì oríṣiríṣi láti fi bu ọlá fún àwọn tó rán án lọ́wọ́ nígbà tí ó ń dàgbà.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Head of jury panel revealed". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-27. Retrieved 2021-08-10.
- ↑ "Peju Layiwola heads LIMCAF's 2016 jury panel". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-26. Retrieved 2021-08-10.
- ↑ "Francis Ikechukwu Okoronkwo - Netizen". artsandculture.google.com. Retrieved 2021-08-08.
- ↑ "Peju Layiwola heads LIMCAF 2016 grand jury panel". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-23. Retrieved 2021-08-10.
- ↑ Nzewi, Ugochukwu-Smooth; Powell, Amy L.; Arndt, Lotte (2012). "exhibition reviews". African Arts 44 (2): 80–87. doi:10.1162/afar.2011.44.2.80. ISSN 0001-9933. https://www.mitpressjournals.org/doi/pdf/10.1162/afar.2011.44.2.80.
- ↑ Nzewi, Ugochukwu-Smooth; Powell, Amy L.; Arndt, Lotte (2011). "Review of Dak'Art 2010". African Arts 44 (2): 80–87. doi:10.1162/afar.2011.44.2.80. ISSN 0001-9933. JSTOR 41330691. https://www.jstor.org/stable/41330691.
- ↑ Okoronkwo, Ikechukwu Francis (2016). Petals And Thorns.. Trafford Publishing. ISBN 978-1-4907-7652-1. OCLC 1152241000. https://www.worldcat.org/oclc/1152241000.