Ikoga jẹ́ abúlé kékeré kan l'órílẹ̀-èdè North-West District of Botswana. Ó súnmọ́ Okavango Delta, ó sì ní ilé-ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ kan. Gẹ́gẹ́ bí ètò-ìkànìyàn ọdún 2001, àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ìlú náà jẹ́ 699.[1]

Ikoga is located in Botswana
Ikoga
Location of Ikoga

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Distribution of population by sex by villages and their associated localities: 2001 population and housing census". Archived from the original on 2007-11-24. Retrieved 2007-12-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)