Ilé ìkàwé Òrílẹ̀ èdè Cameroon

Ilé ìkàwé orílẹ̀ èdè Cameroon jẹ́ ilẹ̀ ìkàwé àgbà ti orílẹ̀ èdè Cameroon (Bibliothèque nationale du Cameroun). Wọ́n da kalẹ̀ ní ọdún 1966, ó sì wà ní Yaoundé.[1]

National Library Cameroon
Ìdásílẹ̀1966
IbùjókòóYaounde

Gégé bí àjọ United Nations ṣe fi léde, ní ọdún 2010, ìdá ọ̀kànléládọ́ta nínú ọgọ́rùn-ún(71%) àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè ni ó le kàwé tí ó sì le kọ.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Yaoundé, Cameroon". Archived from the original on 2012-09-07. Retrieved 2023-05-07. 
  2. "Adult literacy rate, population 15+ years (both sexes, female, male)". UIS.Stat. Montreal: UNESCO Institute for Statistics. Retrieved 25 August 2017.