Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀

Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tí a lè ṣe ìkékúrú rẹ̀ sí (TSP) jẹ́ ilé iṣẹ́ tí ó eà ní ọ̀nà bí a ṣe lè rí ara ẹni bá sọ̀rọ́, yálà nípa lílo ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́, tàbí ìtàkùn ayélujára. [1] [2] Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tàbi TSPs, ni ó jẹ́ wípé nígbà kan rí, ìjọba orílẹ̀-èdè nìkan ló ma ń ṣàkóso lórí pípèsè irúfẹ́ ohun èlò ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ nítorí owó tabua tí ó má ń náni láti pèsè rẹ̀. Àmọ́ nkan ti yí padà tí àwọn ilé-iṣẹ́ aládàáni náà ti ń pèsè àwọn ohun èlò yí. [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Telecom Service Providers (TSP) And Their Industry Responsibilites". DPS Telecom. Retrieved 2020-02-25. 
  2. "Telecommunications Service Priority". Federal Communications Commission. 2011-02-09. Retrieved 2020-02-25. 
  3. "Telecommunications Service Priority (TSP)". CISA. 2020-01-23. Archived from the original on 2020-02-25. Retrieved 2020-02-25.