Ilé iṣẹ Rádíò ìpínlẹ̀ Ogùn
Ilé iṣẹ́ Rédíò ìpínlẹ̀ Ogùn tí ìgé kúrú rẹ̀ jẹ́ OGBC jẹ́ ilé iṣẹ́ ìjọba ti Ìpínlẹ̀ Ògùn
Broadcast area | Ogun State |
---|---|
Frequency | FM: 90.5 |
First air date | 2 Oṣù Kejì 1977 |
Format | News, talk, and drama |
Language(s) | English |
Owner | Ogun State Government |
Webcast | FM |
Website | Official website |
[1] Olú ilé iṣẹ́ náà fìdí kalẹ̀ sí Ìbarà ní ìlú Abẹ́òkútatí ó jẹ́ olú ìle ìpínlẹ̀ Ògun ní apá ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Orì ìkànì 90.5FM àti 92.80 ni wọ́n ti ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́. Wọ́n dá ilé iṣẹ́ náà kalẹ̀ ní ojọ́ Kejì oṣù Kejì, ọdún 1977 (February 2, 1977) gẹ́gẹ́ bí ilé isẹ́ rédíò ti ìjọba.[2]
Ẹ tún le wo
àtúnṣe- Ogun State Television