Ilé isé Innoson olùpèsè okò

Ilé isé olùpèsè okò Innoson ti orílè èdè Nàîjíríà, tí eon we àgékúrú rè sí IVM, jé ilé isé tí ó n pèsè orísirísi ohun amurînà gégé bí okò akérò, okò igbafé ní orílè èdè  Nàîjíríà.. Ògbéni Innocent Chukwuma ni ó jé olùdásílè tí ó sì n se àmójútó ilé isé náà ní ìlú Nnewi ní ìpínlè Anambra.[1][2]

Ìdá ogórin (70%) àwon èyà ara okò ni wón n pèsè fúnra won lábélé ,[3] nígbà tí wón n kó àwon èyà ara okò tókù wolé láti ilè òkèrè bí ilè Jamaní (Germany), ilè Jàpáànù (Japan) àti ilè Sáínà (China) .

Ẹnu ọ̀nà àbáwọlé ilé isé Innoson

Lára àwon irúfé okò tí wón n se jáde níbè nílé isé IVM ni: okò oníjölòókòó márùún a (five-seaters) Fox, tí ó n lo ìwòn epo (1,5 liter engine) àti èyí tí wón pè ní Umu tí  enjìnì rè jé oní jálá epo méjì (2 liter engine) , pèlú okò ayókélé kékeré tí ó n jé Uzo.[4]

Àwon ìtóka sí àtúnṣe

Fáìlì:INNOSON Vehicle logo.jpg
  1. "About Us". Innoson Group. Archived from the original on 2015-11-01. Retrieved 2015-10-29. 
  2. "Innoson rolls out 500 made in Nigeria cars today". Sun News. 2014-11-29. Retrieved 2015-10-29. 
  3. Empty citation (help) 
  4. "Roll-out for first made-in-Nigeria cars". African Business. 2015-03-07. Retrieved 2015-10-29. 

Àwon ìjásóde àtúnṣe