Wẹ̀rẹ̀
(Àtúnjúwe láti Ilée wèrè)
Wèrè jẹ́ ènìyàn kan tí kò gbádùn tàbí tí a lẹ̀ wí pé kò mọ ohun tó ń ṣe mọ.[1]
Ilée wèrè
àtúnṣeilée wèrè jẹ́ ilée kan tí ó jẹ́ wí pé oríṣiríṣi nǹkan ni ènìyàn máa ń bá níbẹ̀. Àwọn nǹkan bíi pàǹtí sáábà máa ń wà níbẹ̀. Àwọn wèrè máa ń sáábà kó àwọn pàǹtí àti nǹkan mìíràn láti ibi tí wọ́n bá ń gbà jọká lọ sí ilée wọn. Ibẹ̀ dẹ̀ lọ máa ń gbé láìní wọ́n lára.[2]
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Definition of mad". www.dictionary.com. 2019-03-12. Retrieved 2022-05-21.
- ↑ "MAD - Meaning & Definition for UK English". Lexico Dictionaries. Archived from the original on 2022-05-21. Retrieved 2022-05-21. Text "English" ignored (help)