Ilẹ̀ọba Bakuba (o tun nje Kuba tabi Bushongo)

Ifáárà: Àwọn kúbà náà ló ń jẹ Bushoong.

ÀÀYÈ WỌN

àtúnṣe

Ààrin gbungban gusu (Congo Zaire) ni wọ́n wà

IYE WỌN

àtúnṣe

Ẹgbẹ̀riún mẹ́tà-dún-lóguń ni wọn

ÈDÈ WỌN

àtúnṣe

Ede Bushhoog ló jẹ́ ẹ̀yà Bàǹtú ni wọn ń sọ

ALÁGÀÁGBE WỌN

àtúnṣe

Biombo, lùbà, kasai, lenda, pyaang, àti Ngongo

ÌTÀN WỌN

àtúnṣe

Awọn Bushoog ni ẹ̀yà tó pọ jù ni kńbà.Baba-ńlá wọn ló tẹ ibẹ̀ dó. Abẹ́ Ìṣèjọba Shyaan kan soso bi gbogbo wọn wà. Òun ló ń darí wọn. Apá ìwọ̀-oòrùn ni wọ́n ti wá sí tí wọ́n etí Máńgò wọn bá àwọn ìwa àti kété sì parapọ̀ ṣe ìjoba kúbà.

IṢẸ́ ỌNÀ WỌN

Àwọn tí ń ṣe iṣẹ́ ọnà tí àwọn adarí ìjọba àti àwọn mẹ̀kúnǹu ń lò bí :-

- Ìlù ìbílẹ̀ tí

- Ìwo tí wọ́n fi n] mu ọti

- Ìjókòó ọba

- Idà ọba

- Ọ̀pá aṣẹ́ àti

- Abẹ̀bẹ̀ ọba

ỌRỌ̀ AJÉ WỌN

àtúnṣe

- Wọ́n ń pẹja

- Wọ́n ń hun aṣọ

- Wọ́n ń dáko pákí, àgbàdo àti ọka ̀ bàbà

- Obiǹrin wọ́n ń ṣòwo ̀ káàkiri agbègbè wọn

ÌṢÈLU WỌN

àtúnṣe

Awọn Bushoog ló ń darí Kuba. Olú ìiú wọn ni Nsheng. Ó le ní ọgọ́ruǹ-ún aṣojú fún ìgbèríko kọ̀ọ̀kan. Òfin ati ìlànà ọba Nyimu wọn ń tẹ̀̀ lé oba shyaam ni ọba àkọ́kọ́. Àwọn ọba mọ́kaǹlélógún ló sì ti jẹ lẹ́yìn rẹ̀. o ti ló iríniwó ọdún ṣẹ́yìn tie ̀tò ìjọba náà ti bẹ̀rẹ.

Ẹ̀siǹ WỌN

àtúnṣe

Bumba ni ẹdá àkọ́kọ́ nínú ìtàn ìgbà ìwáṣẹ̀ won. Òun ló fí awọn Bushoong se asíwájú àti olórí -Ẹ̀sin Baba ńlá wọn ni wọn ń sìn. Ẹ̀sín ọ̀ún ti ń ku lọ díẹ̀díẹ̀. Síbẹ̀, Ìfá tabi Adábigbá ń gbé láàrin wọn. Wọn gbà pè òròṣà ló ko oríre bá wọń. Ère ajá ni wọṅ ń sí ojúbọ òrìsà wọṅ . Ère yìí ló dúró bí olúgbàlà wọn.