In-Young Ahn jẹ́ onímọ̀ ìjínlẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè South Korea. Ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Korea tí ó maa kọ́kọ́ dé Antarctica, ó sì jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó Antarctic (King Sejong Station).[1][2][3] Ó jẹ́ onímọ̀ ìbáṣepọ̀ oun ẹlẹ́mì ìsàlẹ̀ omi àti agègbè wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀gá onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwádí fún Korea Polar Research Institute.[4][5]

In-Young Ahn
Ọmọ orílẹ̀-èdèSouth Korean
PápáAntarctic Marine Ecology
Ilé-ẹ̀kọ́South Korean Polar Research Institute (KOPRI)
Ibi ẹ̀kọ́State University of New York at Stony Brook
Ó gbajúmọ̀ fúnObìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Korea tí ó maa kọ́kọ́ dé Antarctica
obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó Antarctic

Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ahn yege nínú ẹ̀kọ́ lati Seoul National University ní ọdún 1982 (nínú Biological Oceanography) ó sì gba PhD rẹ̀ nínú Coastal Oceanography lati State University of New York ní  Stony Brook ní ọdún 1990. Ahn bẹ̀rẹ̀ ìwádí rẹ̀ ní Korean Polar Research Institute (KOPRI) ní Ọjọ́ kínín Oṣù keje Odún 1991.[2]

Career and impact

àtúnṣe

Ahn wá ní ìdí ètò ìṣàmójútó àyíka ní  King Sejong Station lati odún 1996 sí 2011, ó sì ṣe ìwádi lati gba ìjìnlẹ̀ dátà tí ó wúlò yíyàn Antarctic Specially Protected Area (ASPA #171) nítòsí ibùdó Korea.

Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tí a yàn

àtúnṣe
  • Ahn, In-Young, et al. "First record of massive blooming of benthic diatoms and their association with megabenthic filter feeders on the shallow seafloor of an Antarctic fjord: Does glacier melting fuel the bloom?" Ocean Science Journal 51. 2 (2016): 273–279.
  • HW Moon, WMRW Hussin, HC Kim, In-Young Ahn*. "The Impacts of climate change on Antarctic nearshore mega-epifaunal benthic assemblages in a glacial fjord on King George Island: Responses and implications." Ecological Indicators 57 (2015): 280–292.
  • Ahn, In-Young, et al. "Growth and seasonal energetics of the Antarctic bivalve Laternula elliptica from King George Island, Antarctica." Marine Ecology Progress Series 257(2003): 99–110.
  • Ahn, In-Young, et al. "Baseline heavy metal concentrations in the Antarctic clam, Laternula elliptica in Maxwell Bay, King George Island, Antarctica." Marine Pollution Bulletin 32.8 (1996): 592–598.
  • Ahn, In-Young. "Enhanced particle flux through the biodeposition by the Antarctic suspension-feeding bivalve Laternula elliptica in Marian Cove, King George Island." Journal of Experimental Marine Biology and Ecology 171.1 (1993): 75–90.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe