India Arie
India Arie Simpson (ọjọ́ìbí October 3, 1975), tó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi India Arie (tàbí india.arie), akọrin àti akọọ̀rọ̀-orin ará Amẹ́ríka.[1] Gbogbo àwọn àwo-orin Arie ti tà iye tó ju mílíọ́mù 3.3 lọ ní Amẹ́ríkà àti mílíọ́mù 10 káàkiri àgbáyé. Ó ti gba She has won four Ẹ̀bùn Grammy mẹ́rin nínú ìpèníyàn 23, èyí tí Àwo-orin R&B Tọ́dárajùlọ wà nínú wọn.[2]
India Arie | |
---|---|
India Arie ní Singapore Winehouse Festival in 2011 | |
Ọjọ́ìbí | India Arie Simpson 3 Oṣù Kẹ̀wá 1975 Denver, Colorado, U.S. |
Orúkọ míràn | India.Arie |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Savannah College of Art and Design |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1999–present |
Parent(s) |
|
Website | soulbird.com |
Musical career | |
Irú orin | |
Labels |
|
Associated acts | |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "On A Spiritual And Emotional Journey – India.Arie And Her Music". EF News International. Archived from the original on 2011-11-08. Retrieved 2011-10-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Grammy Winner India Arie is coming to Nigeria in June". Bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 May 2016. Retrieved 2018-12-02.