International Hockey Federation

Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the governing body of field hockey. Fún the governing body of ice hockey, ẹ wo: International Ice Hockey Federation.

Àdàkọ:More citations needed

International Hockey Federation
Logo
AbbreviationFIH
MottoFairPlay Friendship Forever
Ìdásílẹ̀7 Oṣù Kínní 1924 (1924-01-07) (100 years ago)
TypeSports federation
Legal statusGoverning body of:
Field hockey
Indoor hockey
Hockey5s
Purpose/focusSport governance
IbùjókòóLausanne, Switzerland
Region servedWorldwide
Ọmọẹgbẹ́140 national associations
Official languagesEnglish, French[1]
PresidentTayyab Ikram[2]
CEOThierry Weil
Main organCongress
AffiliationsInternational Olympic Committee
WebsiteFIH.hockey

International Hockey Federation tí a gé kúrú tí gbogbo èèyàn sì mọ̀ sí FIH, ó jẹ́ àjọ tó ṣe àmọ́jútó èrè bọ́ọ̀lú aláfìgigbá ni orí pápá àti nínú yàrá ìyẹn is the (field hockey) àti (indoor field hockey). káàkiri àgbáyé. Àwọn olú iléeṣẹ́ wọ́n wà ní Lausanne, Switzerland. FIH ni ó ń má rí sí àwọn ìdíje eré bọ́ọ̀lù aláfigigbá hockey ní àgbáyé, bí ti ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé Hockey (Hockey World Cup).

Wọ́n dá FIH sílẹ̀ ní ọjọ́ keje oṣù kìiní ọdún 1924 ní Paris, Paul Léautey ló gbé àjọ yìí kalẹ̀, tí ó sì padà wá jẹ́ ààrẹ àkọ́kọ́ fún àjọ náà, láti ṣe ìdáhùn sí àwọn àṣìṣe eré idárayá hockey nínú èto kan tí wọ́n pè ní 1924 Summer Olympics.[3] Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n darapọ̀ mọ́ àwọn tó da sílẹ̀ ní Austria, Belgium, Czechoslovakia, France, Hungary, Spain, àti Switzerland.

Ní ọdún 1983, FIH darapọ̀ mọ́ International Federation of Women's Hockey Associations (IFWHA), tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1927 nípasẹ̀ Australia, Denmark, England, Ireland, Scotland, South Africa, the United States, àti Wales.

Ilé iṣẹ́ náà wà ní Lausanne, Switzerland láti 2005, kí wọ́n kúrò níbẹ̀ lọ sí Brussels, ní Belgium.

Ní ìdáhún sí ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé ní Russia àti Ukraine 2022 Russian invasion of Ukraine, FIH ò gba Russia láàyè láti kópa nínú 2022 Women's FIH Hockey Junior World Cup, tí wọn ò sì gba àwọn alákoso Russian àti Belarusian láàyé sí ṣíṣe tàbí ètò FIH kan[4]

Structure

àtúnṣe
 
Map of the World with the five confederations.

In total, there are 140 member associations within the five confederations recognised by FIH. This includes Great Britain which is recognised as an adherent member of FIH, the team was represented at the Olympics and the Champions Trophy. England, Scotland and Wales are also represented by separate teams in FIH sanctioned tournaments.

     AfHF – African Hockey Federation
     AHF – Asian Hockey Federation
     EHF – European Hockey Federation
     OHF – Oceania Hockey Federation
     PAHF – Pan American Hockey Federation

The FIH World Rankings was updated once after the major tournament finished, based on FIH sanction tournaments.

Presidents

àtúnṣe

The following is a list of presidents of FIH:[5]

Presidents of FIH
No. Name Country Took office Left office Note
1 Paul Léautey   France 1924 1926
2 Frantz Reichel   France 1926 1932
3 Marc Bellin du Côteau   France 1932 1936
4 Georg Evers   Germany 1936 1945
Robert Liégeois   Belgium 1945 1946 Acting
5 Jaap Quarles van Ufford   Netherlands 1946 1966
6 Rene Frank   Belgium 1966 1983
7 Étienne Glichitch   France 1983 1996
8 Juan Calzado   Spain 1996 2001
9 Els van Breda Vriesman   Netherlands 2001 2008
10 Leandro Negre   Spain 2008 2016
11 Narinder Dhruv Batra   India 2016 2022
Seif El Dine Ahmed   Egypt 2022 2022 Acting
12 Tayyab Ikram   Macau 2022 Incumbent

Recognition and awards

àtúnṣe

The Player of the Year Awards have been given annually since 1998 for men and women, while the young category was added in 2001 to honour the best performances for junior players (under 21).

Another award, the "Honorary Award", was given to people who have made outstanding contributions to field hockey.

FIH tournaments

àtúnṣe
Major
Junior
Other

Title holders

àtúnṣe
Current
Competition Men's Women's
Olympics Àdàkọ:Fh (2020) Àdàkọ:Fhw (2020)
World Cup Àdàkọ:Fh (2023) Àdàkọ:Fhw (2022)
FIH Pro League Àdàkọ:Fh (2022–23) Àdàkọ:Fhw (2022–23)
Junior World Cup Àdàkọ:Fhu (2021) Àdàkọ:Fhwu (2022)
Youth Olympics Àdàkọ:Fhu (2018) Àdàkọ:Fhwu (2018)
Indoor World Cup Àdàkọ:Idh (2023) Àdàkọ:Idhw (2023)

Partners

àtúnṣe

The following are the partners of the International Hockey Federation:[6]

See also

àtúnṣe

References

àtúnṣe
  1. "International Hockey Federation Statutes" (PDF). FIH. Archived from the original (PDF) on 12 August 2011. Retrieved 28 October 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Tayyab Ikram (MAC) elected as new President of FIH". FIH. Retrieved 5 November 2022. 
  3. Sathe, Mukund. "Paul Léautey". This Day in History (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-01. 
  4. "FIH reiterates full support to Ukraine’s hockey community". FIH. 2022-03-18. Retrieved 2022-03-22. 
  5. "Hockey". Olympedia. Retrieved 16 December 2022. 
  6. "International Hockey Federation". FIH. Retrieved 28 October 2012. 
àtúnṣe
  • [http:// Official website]

Àdàkọ:National members of the International Hockey Federation Àdàkọ:International field hockey Àdàkọ:International Sports Federations Àdàkọ:Authority control