Àjọ Ètò Owó Káríayé

(Àtúnjúwe láti International Monetary Fund)

Coordinates: 38°54′00″N 77°2′39″W / 38.90000°N 77.04417°W / 38.90000; -77.04417

Àjọ Ètò Owó Káríayé (AEOK; International Monetary Fund, IMF) je agbajo kariaye to n mojuto sistemu inawo lagbaye nipa titele awon ipinu makroekonomi awon orile-ede omo egbe re, agaga awon ipinu to nipa lori osuwon pasiparo owo ati ibamu awon isanwo. O je didasile lati se imuro sinsin awon osuwon pasiparo owo kariaye ati lati segbowo idagbasoke.[1] Oluile-ise re wa ni Washington, D.C., Amerika.

International Monetary Fund
The official logo of the IMF
TypeInternational organization
IbùjókòóWashington, D.C.
United States
Ọmọẹgbẹ́187 countries
Managing DirectorÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan John Lipsky (acting)
Main organBoard of Governors
Websitehttp://www.imf.org


Itokasi àtúnṣe