International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies
Àjọ International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies (FIIAPP) ni ò jẹ́ àjọ gbogbo gbo tí wọ́n dá sílẹ̀ ni abe Spanish State and a member institution of Cooperación Española, lati ọwọ́ orílẹ̀-èdè Spain .[1] Àjọ yí ni ó ti ṣe ìkúnlápá nípa ṣíṣàgbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe oríṣiríṣi jákè-jádò àgbáyé, FIIAPP ni ó ń ṣiṣẹ́ labẹ àṣẹ Spanish foreign policy.
FIIAPP_LOGO.png | |
Founded | 1998 |
---|---|
Headquarters | Madrid, Spain |
Area served | Worldwide |
Industry | Public organization |
Owner(s) | Government of Spain |
Website | fiiapp.org |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeAjọ yi ni wọn bẹ̀rẹ̀ wọn dá silẹ̀ ní ọdún 1998 lábẹ́ orúkọ Ibero-American Government and Public Policy Foundation, [Fundación Iberoamericana de Gobierno ́y Políticas Públicas], pẹ̀lú ìrankàn àti ṣíṣẹ pẹ̀lú àwọn àjọ àwùjọ gbogbo. Ní ọdún 2000, wọ́n jàn án pọ̀ mọ́ Ibero-American Institute of Public Administration Foundation [Fundación Instituto Iberoamericano de Administración Pública] (tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1997), tí ó jé kí ó di International and Ibero-American Foundation for Administration and Public Policies (FIIAPP).
Lóní, FIIAPP ti di ọ̀kan gbòógì nínú àwọn àjọ tí ó ṣe agbátẹrù fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe oríṣiríṣi fún àjọ European Union ati Spanish Ministry of Foreign Affairs and Cooperation.
Ẹ tún lè wo
àtúnṣehttp://www.fiiapp.org/ FIIAPP international cooperation projects- http://www.fiiapp.org/proyectos/
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ BOE, State Action and Foreign Service. "Act 2/2014, of 25 March, on State Action and Foreign Service" (in spanish). http://www.boe.es/boe/dias/2014/03/26/pdfs/BOE-A-2014-3248.pdf.