Ipa àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórí eré orí ìtàgé

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní à bá máa pè ní bàsàjẹ́ nítorí kò sí abala ìgbé ayé tí kò ṣe àkóbá fún láti ìgbà tí ó ti bẹ́ sílẹ̀ láti ọdún 2019. Covid-19 ṣe àkóbá lọ́pọ̀pọpọ̀ fún gbogbo abala ère orí ìtàgé. Nítorí Ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ àti títìpa àwọn gbọ̀ngán ìpéjọpọ̀ àwọn eléré orí ìtàgé kò lè ní àǹfàní láti kẹ́kọ̀ọ́ ìgbaradì tàbí láti tẹ́ pẹpẹ àfihàn ere orí ìtàgé wọn. Nítorí ìdí èyí, púpọ̀ nínú àwọn eléré ìtàgé wá ọ̀nà àbáyọ tuntun nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. Èyí ló mú wọn bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àfihàn àwọn abala pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́ẹ́ nínú àwọn àkálẹ̀ àwọn sinimá àgbéléwò, ijó tàbí àwọn ère mìíràn tí wọ́n ti ṣe sẹ́yìn lórí ẹ̀rọ ayélujára. Èyí ni àwọn oníṣẹ́ yóò ṣe àkójọ wọn.[1][2][3] pẹ̀lú àwọn ìpolówó ọjà pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́ẹ́ lórí ìkànnì ayélujára.[4][5]

A theater marquee in Mount Pleasant, Michigan promotes social distancing

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The best theatre to watch online right now". Time Out Worldwide (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-04-06. Retrieved 2020-04-07.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Convery, Stephanie; Rawson, Sharnee (2020-03-20). "Livestreaming schedule: music, art, literature and events from Australia and beyond" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/lifeandstyle/2020/mar/20/livestreaming-schedule-music-art-literature-and-events-from-australia-and-beyond. 
  3. "Stage shows, musicals and opera you can watch online now for free | WhatsOnStage". www.whatsonstage.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-04-09. Retrieved 2020-04-09.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Unitt, Chris. "Cultural Digital: Streams". streams.culturaldigital.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-04-10. Retrieved 2020-04-10. 
  5. "Free Theatre Screenings – Google Drive". docs.google.com. Retrieved 2020-04-10.