Agbègbè Àrin-Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà

(Àtúnjúwe láti Ipinle Mid-Western, Nigeria)

Agbegbe Mid-Western je ipin ile ni Nigeria lati 1963 de 1967. Ni 1967 o yi oruko pada di Ipinle Mid-Western titi di 1976 nigba to di Ipinle Bendel. Ni 1991 o je pinpin si Edo ati Delta.