Irene Ogutu jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 14, óṣu June ni ọdun 1987. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi Defender fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu[1][2][3]

Irene Ogutu
Personal information
OrúkọIrene Awuor Ogutu
Ọjọ́ ìbí14 Oṣù Kẹfà 1987 (1987-06-14) (ọmọ ọdún 37)
Ibi ọjọ́ibíUkwala, Nyanza Province
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Oserian F.C.
National team
Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Irene kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2016[4].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.cosafa.com/kenya-name-coach-provisional-squad/
  2. https://nairobinews.nation.africa/starlets-commence-journey-to-rio/
  3. https://tisini.co.ke/tag/irene-ogutu/
  4. https://allafrica.com/stories/202004200198.html