Isa Ali Ibrahim tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí i Isa Ali Pantami, jẹ́ olóṣèlú àti onímọ̀ Islam, tó fìgbà kan jé Mínísítà Communications and Digital Economy láti ọdún 2019 wọ ọdún 2023. Bákan náà ni ó fìgbà kan jẹ́ Olùdarí àgbà fún National Information Technology Development Agency (NITDA) ní Nàìjíríà láti 26 September 2016 wọ 20 August 2019, kí wọ́n tó yàn án sípò Mínísítà ní 21 August 2019.[1][2][3]

Isa Ali Pantami

FNCS, FBCS, FIIM, MCPN, CON.
Minister of Communications and Digital Economy
In office
21 August 2019 – 29 May 2023
AsíwájúAdebayo Shittu
Arọ́pòBosun Tijani
Director General of the NITDA
In office
26 September 2016 – 20 August 2019
AsíwájúPeter Jack
Arọ́pòInuwa Kashifu Abdullahi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Isa Ali Ibrahim

Gombe State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Flag of Nigeria
ẸbíMarried
ResidenceAbuja
Alma mater

Pantami wà láàárín àwọn òǹkàwé méje (associate professors) ti Governing Council ti Federal University of Technology Owerri (FUTO) tí wọ́n fún ní ìgbéga láti di Professor lásìkò ìpàdẹ́ 186th rẹ̀ tí wọ́n ṣe ní Friday, 20 August 2021.[4][5][6][7] Àmọ́ ṣá, ìgbéga yìí mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdìtẹ̀ wá, èyí tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n kan sọ pé kọ̀ ì yẹ kí wọ́n gba ìgbéga náà, nítorí kò tẹ̀lé ìlànà gbígba irúfẹ́ ìgbégba bẹ́ẹ̀. Lásìkì tí ọ̀tẹ̀ yìí pọ̀ gan-an, a ò gbọ́ ọ̀rọ̀ kankan lẹ́nu Pantami.[8][9]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Buhari swears in ministers (LIVE UPDATES)". Premium Times. 21 August 2019. https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/347756-buhari-swears-in-ministers-live-updates.html. Retrieved 21 August 2019. 
  2. "21 August 2019". Punch Newspapers. 21 August 2019. https://punchng.com/live-updates-ministerial-swearing-in/. Retrieved 21 August 2019. 
  3. Meet the New NITDA Director-General-Dr Isa Ali Pantami Archived 30 September 2016 at the Wayback Machine., Sahara Standard
  4. "Communications Minister, Pantami Becomes Professor of Cyber Security". PRNigeria. 6 September 2021. https://prnigeria.com/2021/09/06/pantami-professor-cyber-security/. Retrieved 8 September 2021. 
  5. "Pantami promoted to professor of cyber security". Guardian Newspapers. 6 September 2021. https://m.guardian.ng/news/pantami-promoted-to-professor-of-cyber-security/. Retrieved 8 September 2021. 
  6. Malumfashi, Muhammad (6 September 2021). "Isa Pantami ya zama Farfesan Jami'a yana rike da kujerar Ministan Gwamnati a Najeriya". legit.hausa.ng. https://hausa.legit.ng/1432907-isa-pantami-ya-zama-farfesa-yana-rike-da-kujerar-ministan-gwamnati-a-najeriya.html. Retrieved 8 September 2021. 
  7. "Aisha Buhari Pantami: President Buhari wife explain why she use Prof. Isa Pantami video on Nigeria security". BBC News Pidgin. 13 September 2021. https://www.bbc.com/pidgin/58542534. Retrieved 19 September 2021. 
  8. "Pantami's fake FUTO professorship joins other intellectual frauds". 11 September 2021. 
  9. "Definitive case against Pantami's FUTO fraudfessorship". 18 September 2021.