Isaac Babalola Akinyele

Oba Isaac Babalola Akinyele, OBE, KBE (April 18, 1882 – May 30, 1964) ni Olubadan akoko to gun ori ite gege bi oba. O gun ori ite ni 1955 o si wa ni be titi di ojo iku re ni 1964ItokasiÀtúnṣe