Isaac Teitei Nortey
Isaac Teitei Nortey jẹ elere tennis ta bi ni ọdun 1999 ti órilẹ ede Ghana to sin gbe ni US. Ni ọmọ ọdun marun dinlogun, Isaac jẹ ọdọmọde elere to pegede julọ ninu idije Junior tennis ti ilẹ afirica[1][2][3][4][5].
Orílẹ̀-èdè | Ghana |
---|---|
Ibùgbé | United States |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Keje 1999 Accra, Ghana |
Ìga | 183 cm |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed, One-Handed Backhand |
Igbèsi Aye elere naa
àtúnṣeNortey ni a bi si Accra, Ghana. Oun kẹkọ lori Igbega ọmọ èniyan ati ẹkọ lóri ẹbi[6][7].
Íṣẹ ati Ipa rẹ gẹgẹbi elere tennis
àtúnṣeNortey bẹrẹ iṣẹ̀ rẹ gẹgẹ̀bi elere afi ẹsẹ gba koto dipè o bẹrẹ sini ṣiṣẹ gẹgẹbi èlèrè tennis nigba to pe ọmọ ọdun meje. Arakunrin naa kọkọ ṣèrè ni Tennis ti Lakedland Galindo. Elere tennis naa ti yege ninu idije mẹfa. Ni ọdun 2019, Nortey wa lara team elere tennis ilẹ ghana to kopa ninu Copu Davis Group IV ni Brazzaville, Congo[8][9][10][11].
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ https://www.tennisexplorer.com/player/nortey-0c11d/
- ↑ https://www.itftennis.com/en/players/isaac-nortey/800366053/gha/mt/S/overview/
- ↑ https://www.atptour.com/en/players/isaac-nortey/n0e5/overview
- ↑ https://www.sofascore.com/team/tennis/nortey-isaac-nortie/220911
- ↑ https://scores24.live/en/tennis/m-06-03-2023-nortey-isaac-nortie-loge-jack-h2h
- ↑ https://www.flashscore.com.ng/player/nortey-isaac/OvbtMgZ6/
- ↑ https://nevadawolfpack.com/sports/mens-tennis/roster/isaac-nortey/4648
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-02. Retrieved 2023-03-08.
- ↑ https://www.modernghana.com/sports/941061/tennis-ghana-to-take-part-in-davis-cup-in-congo-brazzaville.html
- ↑ https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/SportsArchive/Ghana-to-compete-in-Davies-Cup-after-years-of-absence-757847
- ↑ https://allafrica.com/stories/201906240670.html