Iṣu

(Àtúnjúwe láti Isu)

Iṣu (Dioscorea) jẹ́ ọ̀gbìn gbòǹgbò onítááṣì tí a lè gbìn nílẹ̀ olóoru, pàápàá jù lọ ní Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà. Nílẹ̀ Yorùbá Iṣu jẹ́ ọ̀gbìn tó ṣe pàtàkì gan-an. A ma ún gbin isu nipa gbi gbin orí isu, o ma ún to àkókò osù mefa is mejila laarin igba ogbin si igba ìkórè isu[1]

Àwòrán ẹ̀yà iṣu kan tí wọ́n pè ní Líásírìín.

A lè jé isu, ásì le fi isu se iyan(oúnje tó gbajumo gan nílè Yorùbá Àwọn iṣu wọ̀nyí bí i D. communis, jẹ́ iṣu olóró. Iṣu jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ń lo ọdún mẹ́ta àti bẹ́ẹ̀ béẹ̀ lọ. A máa ń gbin iṣu láti jẹ ẹ́ bí i oúnjẹ, pàápàá jù lọ, ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.[1] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣu ni ó wà nítorí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àgbẹ̀ ní ń gbin iṣu.[1]

Àwọn Ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named cabi
  1. >=1#:~:text=Depending%20on%20the%20variety%2C%20yams,only%20one%20crop%20is%20harvested. "Harvesting and storing yams". New Zealand Digital Library. Retrieved 2022-02-24.