Itan Ijapa ati Aja
Iyán mu ni ilù awọn ẹrankó ni ìgbà kan ti awọn ẹranko naa sin ku.Ijàpà lọba ọrẹ rẹ Àjà fun iranlọwọ lóri óunjẹ fun ìdilè rẹ. Awọn mèjejì jọ gbimọ pọ lati lọ ji Iṣù ninu ókó. Nigba ti wọn dè inu ókó, Ajà gbè iwọn ibà iṣu ti ò lè gbè ṣugbọn Ijàpà gẹgẹbi ọlọgbọn ẹwẹ ati òlòju kòkòrò kọja ayè rẹ pẹlu gbigbè iṣu tó kọjà àgbàrà rẹ[1].
Ijapa pè Ajà ki ò duró dè sugbọn kòda lóun. Kópẹ ni ólókó ba ijapa nibẹ ti ó sigbè lọsi ilè ọba. Nigbà ti ọbà bèrè bi ijapa ṣè dè idi ókó ólókó ó nipè aja ló mu óun lọ sibẹ. Ọbà sini ki wọn ló pè àjà wa, ṣugbọn ki awọn ẹmẹwa ọba to dè ilè àjà, ò ti da ina o si fi èpò ra ara ti ó si fi àṣọ bó ara rẹ pẹlu. Nigbà ti àjà dè ilè ọba ó sọfun ọba wipè ara óun koya laipẹ aja bi ni iwaju ọba (Ó ti fi ẹyin si ẹnu ki ó tó dẹ ọdọ ọba) èyi ló mù ki ọba gbà àja gbọ ti ó sini ki ò ma lọ si ilè rẹ. Ọbà pàṣẹ kì wọn fì iya jẹ Ìjapà pẹlù kiki irin gbigbòna si idi rẹ ti ti yó fi ku[2].
Órin inu itan naa
àtúnṣeAjà durò ranmi lẹru fẹrẹ kufẹ
Bi ó bà durò ranmi lẹru fẹrẹ kufẹ
Mà kigbè òlòkò àgbọ
Àgbèwadé fẹrẹ kùfẹ[1]
Ẹkọ lóri itan naa
àtúnṣe- Ójùkókóró kóda
- Ólè ó dà
- Irọ ó dà