Itoro Umoh-Coleman (ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 1977) jẹ́ òní ère ìdárayá ọmọ orílẹ̀-èdè Amerika àti agbábọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá tẹ́lẹ̀rí fún ẹgbẹ́ WNBA. Ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Clemson Tigers ní ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé, ó sì jé adarí ẹgbẹ́ náà.[1][2] Ní ọdún 2002, Atlantic Coast Conference yan Itoro fún '50-year all star women's basketball team,' àti fún '25th Anniversary Tournament' team[3]

Itoro Umoh-Coleman
Guard
Personal information
Born21 Oṣù Kejì 1977 (1977-02-21) (ọmọ ọdún 47)
Washington, D.C.
NationalityAmerika
Listed height5 ft 7 in (1.70 m)
Listed weight140 lb (64 kg)
Career information
High schoolHephzibah (Hephzibah, Georgia)
CollegeClemson (1995–1999)
NBA draft1999 / Undrafted
Pro playing career2003–2003
Career history
2003Houston Comets

Ìgbé ayé ìbéèrè pẹpẹ

àtúnṣe

A bí ní Washington, D.C., Umoh-Coleman dàgbà ní Hephzibah, Georgia. Ó lọ sí Hephzibah High School, ó sì gbá bọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá fún ẹgbẹ́ the Lady Rebels lábẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá Wendell Lofton.[4] Ó ka ẹ̀kọ́ gboyè ní ọdún 1995. [5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. WNBA Player Bio Archived 2011-05-25 at the Wayback Machine.
  2. "Clemson fires Itoro Coleman". ESPN. March 8, 2013. Retrieved 8 Mar 2013. 
  3. "Overtime", Augusta Chronicle, 5 May 2005. Retrieved 03-03-2009.
  4. Tim Morse, "Discipline key to Hephzibah's success", Augusta Chronicle, January 18, 1999. Retrieved 03-03-2009.
  5. Tim Morse, "Discipline key to Hephzibah's success", Augusta Chronicle, January 18, 1999. Retrieved 03-03-2009.