Iwe, jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí iṣẹ́ rẹ̀ dá lórí lílọ̀ oúnjẹ tí a jẹ nínú tí ó ti dà nínú púpọ̀ ẹranko. Ẹ̀yà ara yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ara.

Iwe adiye

Ìrísí rẹ̀ àtúnṣe

Iwe rí roboto, tinú tẹ̀yìn rẹ̀ jẹ́ kìkì iṣan tí ó sì ma ń lọ óúnjẹ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn òkúta wẹ́wẹ̀wẹ́. [1]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Gizzard". Merriam-Webster Online Dictionary. Retrieved 2009-02-05.