Iwon ese bata
Iwon ese bata wà lára nkan ìwon ti won fi ún won gigun nkan, aami re ni '. Lati ìgbà ti àwon orílè-èdè agbaye ti fi ohun sokan lori awon nkan ìwon ní odun 1959, ìwon ese bàtà ti jé dede mita 0.3048. Ni iwon awon Amerika àti Britain, ìwon esè bàtà kan jé dédé insi(inch) mejila, o sí tún jé idasi-meta yardi kan.[1][2]
Ní ayé atijo, ìwon bata esè wà lara àwon ohun ìwòn ni orílè-èdè Griki, Romu, China, Fransi àti àwon orílè-èdè Englisi. Sùgbón gigun ìwon yí yàtò láti orílè-èdè sí orílè-èdè àti làti ìlú sí ìlú.
Àwọn Itokasi
àtúnṣe- ↑ "How many inches are in a foot – inches to foot conversion". howmanyarethey – An encyclopedia of metrics. September 13, 2022. Archived from the original on October 10, 2022. Retrieved October 10, 2022.
- ↑ "How many feet in a yard - 1 yard to feet". RapidTables.com. Retrieved October 10, 2022.